vi
Libros
Ashok Kumawat

Lati Inu Dáyárì Ọmọ Kilásì Àárin Kan

Àpèjúwe Kúkúrú
Ninu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.
Àpèjúwe Ní Kíkún

50 páginas impresas
Propietario de los derechos de autor
Tektime
Publicación original
2021
Año de publicación
2021
Editorial
Tektime
¿Ya lo leíste? ¿Qué te pareció?
👍👎
fb2epub
Arrastra y suelta tus archivos (no más de 5 por vez)